India di orílẹ̀-èdè kẹrin tí yóò wọ inú òṣùpá lágbàyé

Oríṣun àwòrán, Getty Images 23 Ògún 2023 Orilẹ-ede India ti darapọ mọ awọn orilẹ-ede to ti tẹ oju oṣupa lagbaye lẹyin ti ọkọ ofurufu rẹ, Chandrayaan-3, balẹ sinu oṣupa. Oṣu…

Read More

Ẹgbẹ́ wa ló gbé Tani Ọlọhun’ ṣùgbọ́n ìjọba ló gbé e wá sí Ilorin, Ẹgbẹ́ tó ń bá Tani Ọlọhun ṣẹjọ́ ní Ilorin ṣàlàyé

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ Play video, “Islam nìkan ni àṣà wa nílùú Ilorin, kí éni tó bá fẹ́ máa bọ odò lọ ibòmíì…

Read More

Ètò ìdìbò sípò ààrẹ̀ ńlọ lọ́wọ́ lórílẹ̀èdè Zimbabwe

Oríṣun àwòrán, Reuters wákàtí 5 sẹ́yìn Awọn ara orilẹede Zimbabwe ti bẹrẹ si ni di ibo lati yan aarẹ tuntun . Eyi n waye pẹlu bi ọwọngogo ṣe gbode kan…

Read More

Kàyééfì! Furera fi ògùn ẹ̀fọn pa ọmọ orogún rẹ̀, ọmọ ọjọ́ mẹ́rin, lará àdúgbò bá figbe ta!

Oríṣun àwòrán, Others wákàtí 8 sẹ́yìn Ọwọ ti tẹ arabinrin ẹni ọdun mẹrinlelogun kan, Furera Abubakar lori ẹsun pe o pa ọmọ iyaale rẹ, ọmọ ọjọ mẹrin. Iwadii fihan pe…

Read More