EFCC nawọ́ gán Hadi Sirika, alákòóso ètò ìrìnàjò òfúrufú tẹ́lẹ̀ lórí ẹ̀sùn lílu ₦7b ní pónpó

24 Ìgbé 2024, 07:22 WAT Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 8 sẹ́yìn Alakooso fun…

Read More

Bàbá, ọmọ àti aládùúgbò kú sí ṣálángá ni Kano

Oríṣun àwòrán, Getty wákàtí 4 sẹ́yìn Baba ẹni ọgọta ọdun kan ti orukọ rẹ n jẹ…

Read More

Bí ìgbẹ́jọ́ kòtẹ́milọ́rùn tí Baba Ijesha pè lórí ẹ̀wọ̀n tó ń ṣe, ṣe lọ rèé

23 Ìgbé 2024 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 2 sẹ́yìn Gbajugbaja adẹrinpoṣonu onitiata, Olarenwaju…

Read More

Yahaya Bello mú $720,000 lápò ìjọba láti sanwó fásitì ọmọ rẹ̀ nílẹ̀ òkèèrè bó ṣe ku ọjọ́ díẹ̀ kó kúrò lórí àléfà – EFCC

Oríṣun àwòrán, Alhaji Yahaya Bello wákàtí kan sẹ́yìn Ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ, EFCC,…

Read More

Remi Tinubu ló ń bá mi wá ọ̀nà àbáyọ sọ́pọ̀ ìpèníjà tó ń kojú mi – Ademola Adeleke

23 Ìgbé 2024 Gomina ipinlẹ Ọṣun, Ademọla Adeleke ti ṣalaye pe gbogbo igba ti oun ba…

Read More

Gbogbo ìgbà tí mo gbé ìpèníjà dé iwájú ìyàwó Ààrẹ Tinubu ló ń bá mi wá ọ̀nà àbáyọ – Gómìnà Ademola Adeleke

Oríṣun àwòrán, Sen Oluremi Tinubu, CON/X 23 Ìgbé 2024, 11:51 WAT Ìgbà tí a ṣe àfíkun…

Read More

Ẹ jẹ́ kí n san N200,000 owó ìtanràn ẹ̀ṣẹ̀ mi fun yín, kí n sì máa lọ sílé – Bobrisky bẹ kóòtù

Oríṣun àwòrán, Bobrisky222/ Instagram 23 Ìgbé 2024, 07:00 WAT Lẹyin ti iroyin jade pe Idris Ọlanrewaju…

Read More

Nàíjíríà kò tíì pegedé tó láti ní Ọ́lọ́pàá ìpínlẹ̀ – Ọ́gá àgbà ọ́lọ́pàá

Oríṣun àwòrán, Nigeria Police Force/Facebook wákàtí 7 sẹ́yìn Ọgaagba ileeṣẹ ọlọpaa orilẹede Naijiria, IGP Kayode Egbetokun…

Read More

Bobrisky pín àga ọ̀fẹ́ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ó tún pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn

Oríṣun àwòrán, Bobrisky ìṣẹ́jú 59 sẹ́yìn Ọkunrin to maa n mura bii obinrin, Idris Olanrewaju Okuneye,…

Read More

Akintoye àti Igboho ń sọ tiwọn ni, àtúntò ni a dúró fún – Afenifere

Oríṣun àwòrán, Akintoye/Igboho 22 Ìgbé 2024 Awọn agba Yoruba kan atawọn onimọ nipa ọrọ to n…

Read More