Ọ̀pọ̀ àwọn tó fẹ́ ràn mí lọ́wọ́ ló fi ìlọ̀kulọ̀ lọ̀ mí, àyàfi Dudu Heritage nìkan

wákàtí 3 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, thesolaallyson Gbajugbaja akọrin ẹmi, Sola Allyson ti darapọ mọ awọn ọmọ…

Read More

Fídíò, Ìyà ń jẹ wá nílé ìwé mi, orí ilẹ̀ là ń ti jókòó ṣe ìdánwò – Akẹ́kọ̀ọ́, Duration 3,35

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ Ondo School Without Chairs: Iléèwé…

Read More

Sunday Igboho kò tíì bọ́ lọ́wọ́ wa, á fi ẹ̀sùn míì kàn-án – Malami

wákàtí 2 sẹ́yìn Bi ina ko ba tan lasọ, ẹj ko le tan lori eekanna. Afaimọ…

Read More

Ọwọ́ Biola Fowosere tẹ afurasí olè tó kó fóònù àti owó rẹ̀

wákàtí 3 sẹ́yìn Ọjọ gbogbo ni ti ole amọ ọjọ kan soso pere ni ti olohun.…

Read More

Ìjọba ẹ má wòran, àjà ilé Aṣòfin tó ń jò le wó lé wa lórí – Aṣòfin sọ̀rọ̀ ṣókè!

wákàtí 3 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, NAtional Assembly Adari awọn ọmọ ile Aṣofin to kerejulo, Ndudi Elumelu…

Read More

Ọ̀run yóò ya bọ́ tí ààrẹ kò bá wá láti ẹ̀kùn gúúsù Nàíjíríà – Joe Igbokwe

22 Owewe 2021 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 5 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, State House…

Read More

Wo èèwọ̀ mẹ́wàá to fi lè bọ́ lọ́wọ́ ewu iná gáàsì

wákàtí 2 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, Shutterstock Fífi afẹfẹ gaasi dana ko fi akoko ṣofo rara, o…

Read More

Tá à bá ti ibodè tó wọ Naijiria, ìyà kò bá jẹ wá lásìkò Coronavirus – Buhari

wákàtí 4 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, UN Aarẹ Muhammadu Buhari ti ni ipa to dara ni bi…

Read More

Kí ló ń fa ikú ọ̀wọọ̀wọ́ lẹ́yìn Davido?

22 Owewe 2021 Oríṣun àwòrán, Instagram/Davido Lagbo amuludun lọwọ yii, eeyan lee sọ pe nnkan ko…

Read More

Ààrẹ tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan ti sọ̀rọ̀ sókè, Ó ní wàhálà Nàìjíríà fẹ̀rẹ̀ gbẹ̀mí ìyá òun

22 Owewe 2021 Oríṣun àwòrán, Getty Images Aarẹ Naijiria nigbakan ri, Goodluck Jonathan ti ṣalaye pe…

Read More