Wo bí àwọn ọmọlẹ́yìn Kristi ṣe ṣàjọyọ̀ ọdún Ajinde káàkiri àgbàyé

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oni, ọjọ kẹtadinlogun, oṣu Kẹrin, ọdun 2022 ni ayajọ ọdun Ajinde ọdun yii.

Ọdun Ajinde ṣe pataki si awọn ọmọlẹyin Kristi kaakiri agbaye nitori ọjọ naa jẹ ọjọ ti wọn maa n ṣeranti ọjọ ti Jesu ji dide ninu oku.

A ti ṣe akojọpọ awọn aworan bi awọn eeyan ṣe ṣe ọdun naa lagbaye.

Aworan bi ọdun Ajinde ọdun 2022 ṣe lọ ree kaakiri agbaye

Happy Easter message 2022:

Oríṣun àwòrán, Inpho

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, AFP

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Facebook/Deeper Life Bible Church

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Other

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Church of Nigeria

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, Reuters

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, EPA

Bi ọjọ ọdun Ajinde ṣe bẹrẹ ree

Gẹgẹ bii ohun ti iwe mimọ sọ ninu majẹmu tuntun, awọn ara Romu lo kan Jesu mọ agbelebu ni nnkan bii 30 A.D., lẹyin naa ni awọn eeyan rẹ sin oku rẹ niluu Jerusalem.

Ni ọjọ kẹta ni Jesu jinde gẹgẹ bo ṣe wa ninu iwe Mathew 28:1-10.

Lẹyin awẹ lẹnti to maa n waye fun ogoji ọjọ ni awọn ọmọlẹyin Kristi kaakiri agbaye maa n ṣe ajọyọ ọdun ajinde ni ọjọ Aiku ‘Easter Sunday.”

Ọjọ “Ash Wednesday” ni awẹ lẹnti naa si maa n bẹrẹ.

Amọ ṣaaju ọjọ ọdun ajinde yii ni awọn Kristẹni maa n ṣe iranti ayayjọ ọjọ ti Jesu gun kẹtẹkẹtẹ wọ ilu Jerusalem, ti wọn n pe ni ” Palm Sunday.”

Ọjọ Ẹti to tẹle “Palm Sunday'” ni ayajọ ọjọ Ẹti rere, iyẹn “Good Friday.”

Happy Easter message 2022

Oríṣun àwòrán, AFP

Kini pataki ọdun Ajinde?

Pataki ọdun Ajinde ni lati sami ijiya ti Jesu Kristi jẹ́ lori igi agbelebu.

Awon onigbagbo tun gbagbọ́ pe o wa lati fi se iranti iku Jesu Kristi lati fun awọ́n elẹ́sẹ̀ ni ominira lati bọ́ lọ́wa igbekun aisi igbala.

O tun wa fun lati sami ayọ́ ati ireti ajinde lẹ́yin oku ti awọ́n Onigbagbọ́ gbagbọ́ ninu re.

Eyi waye leyin ti Jesu Kristi jinde lọ́jọ́ kẹ́ta kuro ninu isa oku ni eyi to je ireti nla pe o ti gba kọ́kọ́ra lọ́wọ́ iku atinisa oku fun enikeni to ba gbagbo ninu re.