Kíní ìtumọ̀ àyájọ́ Ọ̀jọ ”Ash Wednesday’ tó wáyé lóní?

Oni ni ayajọ ọjọ eeru ”Ash Wednesday” ti awọn onigbagbọ, ọmọ lẹyin Kristi n parapọ lati ṣe ayajọ ọjọ naa.

Ayajọ ọjọ ti awọn ọmọlẹyin Kristi ka si ọjọ mimọ, ti wọn yoo fi eeru si iwaju ori wọn, ti wọn yoo si tẹsiwaju lati jẹ ẹran

Wo bí wọ́n ṣe sàmì Ọjọ́rùú eérú ”’Ash Wednesday’ tọdún 2021 ni àwon ibìkan