NÍ YÀJÓYÀJÓ Ìbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Eko ní ọwọ́ ẹlẹ́yàmẹ̀yà nínú – Ìjọba Amẹ́ríkà

Copyright: Collage

Oludije sipo gomina labeͅ eͅgbeͅ oselu APC,
Teslim Folarin ti ki Seyi Makinde ti eͅgbeͅ oselu APC woͅle geͅgeͅ bi gomina
fun saa keji ku oriire.

Folarin kii ku oriire ninu ateͅjade to fi
lede leͅyin ti ajoͅ eleto idibo INEC kede Makinde geͅgeͅ bi eͅni to jawe olubori ninu idibo sipo gomina to waye
naa.

Bakan naa ni Folarin ki awoͅn alatileͅyin
reͅ ti woͅn tu jade lati wa dibo fun lasiko ibo woͅn, to si ni oun moͅ lore.

‘’Mo dupeͅ loͅwoͅ awoͅn adari eͅgbeͅ ati
awoͅn oͅmoͅ eͅgbeͅ oselu APC ati gbogbo awoͅn oͅmoͅ eͅgbeͅ oselu miran to
sͅisͅeͅ peͅlu wa, gbogbo woͅn ni mo dupeͅ loͅwoͅ yin patapata.

‘’Bakan naa ni modupeͅ loͅwoͅ igbimoͅ ipolongo
idibo sipo aaareͅ ati gomina ni eͅgbeͅ osͅelu APC fun atileͅyin woͅn ni gbogbo
naa.’’

‘’Mo dupeͅ fun atileͅyin yin ati igbagboͅ
ninu mi pe mo le sͅe, ti eͅ si duro ti mi patapata lai weͅyin, mo dupeͅ loͅwoͅ
yin.’’

‘’Igbagboͅ mi ni pe Oͅloͅrun lo n fun
eniyan ni ipo, to si n gba pada ni oͅwoͅ eniyan, adura mi nipe ki awoͅn ara
ipinleͅ Oyo ati ipinleͅ Oyo maa teͅsiwaju.’’

‘’Amoͅ mo feͅ ki eͅ ni suuru lasiko yii, ki
a si wo bi esi idibo naa se ri, ki a to gbe igbeseͅ kankan’’