Fídíò, Wo ohun tó fa ìjà Ukraine àti Russia pẹ̀lú bí o se kàn ọ́ báyìí, Duration 4,13

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ukraine and Russsia crisis: Aáwọ̀ tó wà láàrin Russia àti Ukraine ti mú àlékún bá iye owó epo rọ̀bì lágbàyé

Ikolu Russi a si Ukraine ti di amojuto gbogbo agbaye bayii

Kí ni ipa tí ìkọlù Russia sí Ukraine le ní lórí ilẹ̀ Adúláwọ̀

BBC Yoruba se agbeyewo ohun to n sele laarin Ukraine ati Russia ati bi o se le ni ipa lori iwo ti o n gbe nile Afrika lori eto Laa Han Mi.

Laa Han Mi

Kini Eto Laa Han Mi lori BBC Yoruba jẹ́?

Eto Laa Han Mi ni a fi n satupale ohun ti ko ye awon ololufe BBC to lasiko to ba n sele.

Laa Han Mi

Ukraine ló ń pèsè oúnjẹ wooro jù lágbàyé, àwọn orílẹ̀ èdè bí i Tunisia, Egypt, Morocco àti Libya yóò mọ ìkọlù láàárín àwọn orílẹ̀ èdè méjéèjì yìí lára púpọ̀.

Bẹẹ ba si gbagbe, aarẹ Putin ti se ikilọ saaju lọsẹ to kọja pe “ẹnikẹni to ba n gbero lati da si aawọ Russi ati Ukraine lati ita – ni oju wọn yoo ri ohun ti oju ẹnikẹni ko ri ri ninu itan.”

Laa Han Mi