Fídíò, Àánú ni mo ṣe láti fẹ́ Duro Ladiipo ṣùgbọ́n kò fi mi sílẹ̀ láti 1962, ọ̀rọ̀ ìfẹ́ wa dùn púpọ̀- Abiodun Duro Ladiipo, Duration 12,04

Moremi: Ti o ba kọ̀ ti oo fẹ́ mi, maa fi ẹjọ́ rẹ sun Olorun …. ni ọrọ ti duro Ladiipo fi dẹnu ifẹ kọ mi nigbẹyin