Àwọn àwòrán tó jojú ń gbèsè nípa àjọ̀dún ìṣẹ̀ṣe tọdún 2023 rèé

Aworan

Awọn ẹlẹsin abalaye peju-pesẹ si ibi ọdun wọn to waye ni ilu Ondo ni Ogunjọ, Osu Kẹjọ, ọdun 2023.

Pẹlu aṣọ alaranbara ni wọn pejọ sibẹ, ti awọn ọmọde ko si gbẹyin nibi ayẹyẹ ọdun Iṣẹṣẹ ni ilu Ondo, nipinlẹ Ondo.

Awọn onilu, onijo, onigba, iya agba, ni wọn wa nibi.

Awọn ọdọ naa peju pesẹ sibẹ ninu aṣọ funfun, pupa ati bẹẹ bẹẹ lọ.Awọn aworan to lamilaaka lati ibi ayẹyẹ naa ree…

Àwọn oníṣàǹgó tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Aworan
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Aworan
Aworan
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe

Àwọn àwòrán míràn tó làmì-laaka níbi ọdún Ìṣẹ̀ṣe tó wáyé lánàá

Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe

Gbogbo ogúnjọ́ oṣù Kẹjọ ọdún ni àwọn oníṣẹ̀ṣe káàkiri ilẹ̀ Yorùbá máa ń parapọ̀ ṣayẹyẹ.

Ọdún yìí kìí yọ ẹnìkankan nítorí àtàwọn tó ń bọ Ọ̀sun, Ṣàǹgó, Èṣù, Ọya, Egúngún àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ni gbogbo wọn máa ń parapọ̀ ṣe ọdún.

Káàkiri ilẹ̀ Yorùbá ni àyájọ́ ọdún mìíràn tún kò ní àná ọjọ́ Àìkú, ogúnjọ́ oṣù Kẹjọ ọdún 2023.

Àkójọ àwọn àwòrán ayẹyẹ náà káàkiri ilẹ̀ Yorùbá rèé:

Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Aworan
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Aworan
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe
Àwọn oníṣẹ̀ṣe tó ń ṣọdún Ìṣẹ̀ṣe