Irọ́ ní ìròyìn pé a fowó kún owó iná – AEDC

Aworan

Oríṣun àwòrán, Others

Ileeṣẹ Abuja Electricity Distribution Company (AECD) ti ni iroyin kan to gba ori ayelujara pe awọn fowo kun owo ina mọnamọna fun awọn onibara wọn lọjọ kini oṣu keje ọdun 2023lo jẹ irọ to jina si otitọ.

Ninu atẹjade kan ti ileeṣẹ ọhun gbe sori ayelujara gba awọn onibara wọn lati yago fun iroyin nitori ko a lati ileeṣẹ naa.

“Ki gbogbo gbọ, a ko buwọlu afikun owo mọnamọna ati a ko si tẹwọgba anfani lati buwọlu. A tọrọ aforijin.”

Aworan

Oríṣun àwòrán, twitter.com/aedcelectricity