Kí ló dé tí Hisbah Kano ṣe fìwé pe Òbí Shatu Garko tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jẹ ‘Miss Nigeria’?

wákàtí 6 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, Shatu Garko Olori ikọ Ọlọpaa ẹsin Hisbah nipinlẹ Kano, Sheikh Harun…

Read More

Ìjọba àpapọ̀ kéde ọjọ́ Aje àti ọjọ́ Iṣẹgun tó ń bọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ìsinmi ọdún Keresimesi

22 Ọ̀pẹ̀̀ 2021 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 3 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, Getty Images…

Read More

Ẹgbẹ́ àwọn olùgbé Magodo Phase 2 gbé kọ́kọ́rọ́ sẹ́nu ọ̀nà iléègbé náà nítorí àwọn ọmọ onílẹ̀

22 Ọ̀pẹ̀̀ 2021 Oríṣun àwòrán, @Nairametrics Ogunlọgọ awọn eeyan to n gbe ni ileegbe Magodo, niluu…

Read More

Olùwọ́de EndSARS kan móríbọ́ lẹ́yìn ọdún kan lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Kirikiri

Iroyin ayọ ree fun awọn oluwọde EndSARS ti awọn agbofinro fi si ahamọ kaakiri awọn ibudo…

Read More

Fídíò, Lásìkò ìsìnmi àti pọ̀pọ̀ṣìnṣìn ọdún yìí, Òbí gbọ́dọ̀ fi àsìkò sílẹ̀ fi tọ́jú àwọn ọmọ wọn, Duration 2,33

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ Akinọla: Ọdún méjì ni kí…

Read More

$5.8bn tí Nàìjíríà tún fẹ́ yá, SERAP ní kí Buhari dẹ́kun owó yíyá

wákàtí 7 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, @serap Ajọ to n gbogun ti iṣowo ilu kumọ kumọ, SERAP…

Read More

Fídíò, Kóníléógbélé Covid 19 ló jẹ́ ká ronú gbé ‘Learn Am’ jáde láti ran àwọn ọmọ Nàìjíríà lọ́wọ́, Duration 6,47

Learn Am App: Kóníléógbélé Covid 19 ló jẹ́ ká ronú gbé ‘Learn Am’ jáde láti ran…

Read More

Èdèàìyedè láàrín Ààrẹ Buhari àtàwọn aṣòfin àpapọ̀ lórí òfin ìdìbò ní Nàìjíríà

wákàtí 2 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, facebook Kikọjalẹ ti aarẹ Muhammadu Buhari kọ lati buwọlu abadofin eto…

Read More

Mu pàrágá wakọ̀ l’Oyo, kóo kó sí gbaga ìjọba

30 Ọ̀pẹ̀̀ 2019 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí 2 sẹ́yìn Oríṣun àwòrán, Other Omi…

Read More

Wò ìdí tí téélọ̀ rẹ fi já ọ kulẹ̀ lásìkò ọdún Kérésìmesì

23 Ọ̀pẹ̀̀ 2019 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí kan sẹ́yìn Asiko ọdun Keresimesi ku…

Read More