Emefiele kéde pé ká máa ná Naira owó àtijọ́ àti tuntun lọ

Oríṣun àwòrán, CBN ìṣẹ́jú 57 sẹ́yìn Banki apapọ lorilẹede Naijiria ti kede pe awọn ara ilu…

Read More

Wo bí ìgbẹ́jọ́ kòtẹ́milọ́rùn láàrin Oyetola àti Adeleke ṣe wáyé ní Akure

Oríṣun àwòrán, Afolabi Henry Adedapo wákàtí 4 sẹ́yìn Ile ẹjọ kotẹmilọrun to wa nilu Akure ko…

Read More

Ọmọ mi ń múra láti lọ kàwé ní UK, kó tó pàdé ikú òjijì nínú BRT – Bàbá Oreoluwa Aina

Oríṣun àwòrán, Oreoluwa Aina 12 Ẹrẹ̀nà 2023 Wọn ti sin oku Oreoluwa Aina, agunbanirọ to jẹ…

Read More

CBN ti pàṣẹ fáwọn báǹkì láti gbà tàbí san Naira àtijọ́ fún aráàlú – Soludo

Oríṣun àwòrán, CBN wákàtí 2 sẹ́yìn Gomina CBN nigba kan ri, Ọjọgbọn Charles Soludo ti fidi…

Read More

Ẹni tí mo ṣe lóore ló gún mi lọ́bẹ ní ọrùn, gún ẹ̀gbọ́n mi ní apá – Portable

Oríṣun àwòrán, Collage ìṣẹ́jú 34 sẹ́yìn Gbajugbaja olorin takasufe, Habeeb Okikiola ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ…

Read More

Boko Haram pa apẹja ọgbọ̀n, UN figbe ta

Oríṣun àwòrán, TWITTER/@PEACOCK wákàtí 2 sẹ́yìn Ajọ iṣọkan agbaye, UN, ti bu ẹnu atẹ lu bi…

Read More

Ìgbà márùn-ún ni mo fi aṣọ pupa kìlọ̀, fọn fèrè fún Dẹrẹba BRT àmọ́ kò dáhùn – Òṣìṣẹ́ rélùwéè

Oríṣun àwòrán, Lagos State Government wákàtí 3 sẹ́yìn Ọkan lara awọn osisẹ ileeṣẹ ìjọba to n…

Read More

”Mo jẹ gbèsè tí apá mi kò ká torí mò ń wá iṣẹ́ ìyanu lọ́dọ̀ pásítọ̀”

wákàtí 3 sẹ́yìn Arabinrin Evarline Okello ti sọ iriri rẹ pẹlu ẹkun kikoro lẹyin to ya…

Read More

Ohun tí amọ̀ nípa ikú Baba Bintin, òṣìṣẹ́ rédíò tó ṣubú lulẹ̀ lásìkò tó ń lọ ibi iṣẹ́ ní Ibadan nìyí

Oríṣun àwòrán, Fresh FM wákàtí 4 sẹ́yìn Òṣìṣẹ́ iléeṣẹ́ rédíò Fresh FM tó wà ní ìlú…

Read More

‘Ta ni yóò tọ́jú mi lẹ́yìn ikú Oreoluwa’ – ìyáìyá àgùnbánirọ̀ tó kú sínú ìjàmbá ọkọ̀ Eko figbe bọnu

Oríṣun àwòrán, Others 9 Ẹrẹ̀nà 2023 Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn wákàtí kan sẹ́yìn Ńṣe…

Read More