Wo iye ìgbà tí Buhari sàbèͅwò sí Eko àti ìdí tó fi wá lótèͅ yìí

Aarẹ Buhari n jade sọkalẹ ninu baalu

Aareͅ orileͅede Naijiria, Muhammadu Buhari yoo maa sabeͅwo si ilu Eko fun oͅjoͅ meji lati sͅI awoͅ isͅeͅ akansͅe to n loͅ loͅwoͅ ni ipinleͅ naa.

Aareͅ Buhari yoo sͅi awoͅn isͅe akanseͅ eleyii ti gomina Babatunde Sanwo-Olu sͅe ni i[inleͅ Eko ati awoͅn isͅeͅ aknsͅe miran.

Lara awoͅn isͅeͅ akanse ti yoo ma si ni Lekki Deep Sea Port, Lagos Rice Mill, opopona tuntun ni agbegbe Eleko si Epe ati ileesͅeͅ John Randle Centre for Yoruba Culture and History.

Amoͅ isͅeͅ akansͅe miran ti aareͅ yoo tun maa sͅi ni ileesͅeͅ MRS Lubricant Factory Apapa and di Blue Line Rail project for Marina.

Bakan naa ni aareͅ yoo wa nibeͅ nigba ti woͅn buwoͅlu ibeͅreͅ ipele keji isͅeͅ oju irin to loͅ lati Mile 2 si Okokomaiko.

Isͅeͅ akansͅe to lamilaaka juloͅ ninu eleyii ti aareͅ feͅ si ni oju agbami Lekki Deep Sea port ati Blue rail Line.

Ijoͅba ipinleͅ Eko ni oju irin ti aareͅ feͅ si n aa ni awoͅn yoo ma lo fun oͅkoͅ oju irin ninu ipinleͅ Eko.

Igba miran ti aareͅ Buhari ti sabeͅwo si ilu Eko

Aarẹ Buhari ati

Oríṣun àwòrán, Presidency

Ni osͅu Keta, odun 2022, aareͅ Buhari wa sͅi ileesͅeͅ Dangote Fertilizer palnt to si wo ibi ti isͅeͅ de duro lori Dangote refinery ati Deep sea port.

Ni Osu Keͅfa, oͅdun 2021, aareͅ Buhari wa sͅI ojuko oju irin Ibadan si Eko ti woͅn sͅeͅsͅeͅ beͅreͅ isͅeͅ.

Ni oͅdun 2019 aareͅ Buhari wa si ile iwosan itoͅju awoͅn oͅmoͅ ati iya ti woͅn sͅeͅsͅeͅ soͅ di ileewosan eͅkoͅni Lagos State University Teaching Hospital (LASUTH)Ikeja.

Bakan naa ni oͅdun 2018 ni aareͅ Buhari wa sͅI ileesͅeͅ Ecowas to wa eͅnu Seme.

Gomina teͅleͅri, Akinwunmi Ambode lo gbalejo aareͅ Buhari nigba naa loͅhun.

Bakan naa ni aareͅ sͅI ibudokoͅ awoͅn oͅkoͅ akero ti ijoͅba ipinleͅ Eko.