Ìfèhóͅnúhàn gbòde kan lórí báǹkì tí kò san owó fún àwoͅn aráàlú

Ibi ifẹhonuhan

Awoͅn afeͅhoͅnuhan kaakiri ipinleͅ Ogun, Oyo ati Benin fi aidunnu woͅn han si airi owo gba ni banki kaakiri orileͅede Naijiria.

Awoͅn afeͅhoͅnuhan naa ni o to gẹ lori aisi owo naira ati oͅwoͅgogo epo beͅntirol to gbode kan.

Iroyin ni oͅpoͅ ninu awoͅn oͅdoͅ to feͅhoͅnuhan naa ni woͅn ti awoͅn agbegbe kan pa ni ilu Ogun.

Eyi lo mu ki oͅpoͅ banki ti ileͅkun woͅn ki awoͅn afeͅhoͅnuhan naa ma ba yaboͅ woͅn ni eͅnu isͅeͅ.

Aworan

Oríṣun àwòrán, Others

Ọmọkunrin kan fara gbọta nibi ifẹhonuhan Abeokuta, awọn banki sare ti ilẹkun wọn

Agbegbe Asero ni ilu Abeokuta ni ifeͅhoͅnuhan ti beͅrͅeͅ leͅyin ti awoͅn onibara ileesͅeͅ Banki GTB ni agbegbe naa ko ri owo gba.

Leͅyin naa ni woͅn dana si aarin ilu, ti woͅn si ti gbogbo oͅna to woͅ Adatan ati agbegbe Osiele-Ibadan.

Ifeͅhoͅnuhan naa tan ka de agbegbe Sapon, Oke-ilewo, Lafenwa, Gbonagun, Obantoko ati awoͅn agbegbe miran.

Eyi mu ki awon osͅisͅeͅ banki ni agbegbe Oke-ilewo ati Pansͅeͅkeͅ fi eͅseͅ feͅ, ti awoͅn ileeͅkoͅ ni agbegbe naa si ti ileͅkun woͅn leͅyin ti awoͅn kan ju tajutaju sibeͅ.

Bakan naa ni koͅmisoͅnna oͅloͅpaa nipinleͅ Ogun ran awoͅn ikoͅ reͅ lati da alaafia pada si ilu.

Gomina ipinleͅ Ogun, Dapo Abiodun naa kesi awoͅn eniyan lati gba alaafia laaye ki woͅn si jeͅ ki ijiroro oun peͅlu awoͅn osͅisͅeͅ banki ati CBN so eso rere.

Koda, ọmọkunrin kan fara gbọta nibi ifẹhonuhan naa, amọ ko sẹni to mọ boya o ti ku tabi o si wa laaye.

Ibi ifẹhonuhan

Oríṣun àwòrán, Screenshot

A ko le maa dakeͅ loͅ bayii, a gboͅdoͅ soͅroͅ soke ni – Awọn Afẹhonuhan nipinleͅ Ondo yari

Awoͅn afeͅhoͅnuhan naa lo jade ni eͅgbeͅgbeͅrun woͅn ti woͅn si di opopona Benin si Ore to fi moͅ Shagamu ni agbegbe Odigbo.

Ohun ti woͅn n beere fun ni ki opin de ba aisi owo ni igboro ati epo beͅntirol to woͅngogo.

Awoͅn afeͅhoͅnuhan naa beͅreͅ si ni koͅrin ominira, ti woͅn si fa sunkeͅreͅ fakeͅreͅ oͅkoͅ loju popo oͅhun.

Oͅkan lara awoͅn oͅdoͅ to soͅroͅ nibi ifeͅhoͅnuhan naa ni a ko le maa dakeͅ loͅ bayii, a gboͅdoͅ soͅroͅ soke.

Amoͅ o sͅeleri pe ifeͅhoͅnuhan ti woͅn n seͅ a loͅ ni iroͅwoͅroͅseͅ, ti awoͅn ko si ba ohun ini kankan jeͅ.

‘’ A ko lee gba owo ni Banki, awoͅn POS n gba owo loͅgoͅoͅroͅ loͅwoͅ wa ki woͅn to fun wa lowo, awoͅn miran tileͅ n sun si banki nitori airi owo jeͅun.’’

‘’Bakan naa ni epo beͅntirol ti di oͅwoͅgogo, ti iya ati isͅeͅ si n ba awoͅn eniyan finra.

Eleyii ti mu ki oͅpoͅloͅpoͅ banki ni ilu Akure ni ipinleͅ naa ti awoͅn ileesͅeͅ woͅn, ti woͅn si ni awoͅn fi imu keͅeͅfi pe o sͅeesͅe ki woͅn se ikoͅlu si awoͅn banki ni ipinleͅ naa.

Ibi ifẹhonuhan

Oríṣun àwòrán, @Muhammad

Sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ waye ni Benin, bi oju popo se di pa lasiko ifẹhonuhan

Awoͅn eͅgbeͅ ajafeͅtoͅ Edo Civil Group ti Agho Omobude jeͅ adari fun ni woͅn ti opopona to loͅ si ileesͅeͅ Banki apapoͅ Naijiria ni agbegbe naa.

Eyi mu ki isͅoro wa fun awoͅn eniyan to n koͅja tabi wa oͅkoͅ loͅ si ibi isͅeͅ woͅn.

Omobude ni igbeseͅ ijoͅba lati yi naira pada fihan pe oͅna lati mu inira ba awoͅn eniyan lorileͅede Naijiria ni.

Amoͅ o ni ipade awoͅn peͅlu CBN nipinleͅ naa fihan an pe awoͅn eniyan yoo ri 200 naira note gba ti woͅn si le gba iye owo to to 20,000 ninu banki.

Nibayii, awoͅn eͅgbeͅ akeͅkoͅoͅ naa ti sͅeleri lati se ifeͅhoͅnuhan kaakiri orileͅede Naijiria ti ijoͅba ko bagbe igbeseͅ lori oͅwoͅngogo epo beͅntirol ati oͅwoͅngogo owo naira to gbode kan.