Fídíò, Wo àwọn ọjà tí o lè fi ṣe pàṣípáàrọ̀ ilé, ẹja àti ǹkan míì ní Nàìjíríà, Duration 1,53

Ojọ Abamẹta nikan ni wọn ma n na ọja yii ni ilu Esuk Mba ni ipinlẹ Rivers ni aarin guugu-guusu Naijiria.

Idahun awọn ibeere yii wa ninu fọnran ifọrọwanilenuwo ti BBc ṣe si ọja paṣipaarọ yii nipinlẹ Rivers.

Ofiong Etim Okon, Arit Ekpo, Merit Akon ati Rosemary Achibong to jẹ kọmiṣọnna okoowo ni ipinle Rivers sọrnọ nipa ọja yii ati pataki rẹ laisko yii.