Fídíò, Iba Gani Adams dáhùn sí ìbéèrè ọ̀pọ̀ ọmọ Yorùbá lórí bóyá nǹkan àmúṣagbára ìṣẹ̀mbáyé ṣì wà, Duration 1,50

“Leṣẹbọ le ṣoogun, baa ti waye paari laari o”.

Ọrọ ti Iba Gani Adams, Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba fi ṣide ọrọ lori ifọrọwerọ rẹ pẹlu BBC News Yoruba lori boya lootọ nnkan agbara ṣi wa.

Iba Gani Adams ni lootọ awọn nnkan ti a n ri ni ayika wa lee maa mu iyemeji wa ori boya agbara nbẹ tabi booya oogun wa, sibẹ awọn ọmọ Yoruba ṣi nilo lati gbagbọ ninu iṣẹṣe wọn.