Àwọn jàndùkú ṣekúpa ọ̀gá àgbà CBN tẹ́lẹ̀rí ní Kaduna, jí èèyàn 50 gbé lọ

Oríṣun àwòrán, getty images wákàtí kan sẹ́yìn Awọn janduku ti ṣekupa eeyan mẹfa o kere tan…

Read More

Ọmọ ọ̀dọ̀ jí N81.6m ọgá rẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́, ẹ wo bí o ṣe fi owó pitú

Oríṣun àwòrán, Nigeria Police Zone 2 Lagos wákàtí 2 sẹ́yìn Ọwọ ṣikun awọn agbofinro ti ba…

Read More

Ìgbìmọ̀ lọ́balọ́ba l’Ogun ni kí Olú Owode lọ rọọ́kún nílé

Oríṣun àwòrán, Facebook wákàtí 2 sẹ́yìn Igbimo lọba lọba nipinlẹ Ogun, ni abẹ adari Alake ti…

Read More

Àwọn àǹfààní tí Zobo le ṣe fún ara rẹ, àti ipa tó le ni lára aláboyún

Oríṣun àwòrán, Getty Images wákàtí 3 sẹ́yìn Ènìyàn kan tó gbajúmọ̀ lórí ayélujára ló gbé fọ́nrán…

Read More

Ètò ọrọ̀ ajé United Kingdom wọ ‘recession’ – Wo nǹkan tí èyí túmọ̀ sí

Oríṣun àwòrán, Getty Images wákàtí 5 sẹ́yìn Iroyin lọdọ awọn alaṣẹ nilẹ Gẹẹsi ti fihan pe…

Read More

Ọwọ́ ọlọ́pàá Ogun tẹ wòólì méjì àti babaláwo méjì tó pa ọ̀dọ́bìnrin kan fún ètùtù ọlà

Oríṣun àwòrán, Ogun State police wákàtí 2 sẹ́yìn Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti tẹ awọn…

Read More

Taa ni Oyetunde Ojo, ọkọ ọmọ Ààrẹ Tinubu tó di alága àjọ FHA

Oríṣun àwòrán, Oyetunde Oladimeji Ojo/Facebook 16 Èrèlè 2024, 14:49 WAT Ìgbà tí a ṣe àfíkun gbẹ̀yìn…

Read More

Kókó mẹ́fà tí Tinubu àtàwọn gómìnà fẹnukò lé láti mú àdínkù bá ọ̀wọ́n gógó

Oríṣun àwòrán, Asiwaju Bola Tinubu/FACEBOOK wákàtí kan sẹ́yìn Ààrẹ Bola Tinubu àtàwọn gómìnà mẹ́rìndínlógójì tó wà…

Read More

Ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo ti ilé ìwòsàn aládàni mẹ́fà pa lórí ẹ̀sùn lílo ayédèrú òṣìṣẹ́

Oríṣun àwòrán, Oyo State Government wákàtí kan sẹ́yìn Ijọba ipinlẹ Oyo ti gbe ile iwosan mẹfa…

Read More

Mọ̀ nípa ìṣèjọba ‘Parliamentary System’ tí àwọn aṣòfin kan ní kí Naijiria padà sí?

Oríṣun àwòrán, NATIONAL ASSEMBLY wákàtí 2 sẹ́yìn Ikọ̀ ẹlẹ́ni àádọ́rùn-ún nínú àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojúṣòfin…

Read More