Ṣé lóòótọ́ ni pé omi mímu kò já ààwẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ àwọn kan?

Oríṣun àwòrán, Others Article information Author, Akinlabi Afolabi Role, Broadcast Journalist wákàtí kan sẹ́yìn Bi oṣu…

Read More

Ikú ṣọṣẹ́! Òṣèré Yorùbá Gbemi Anjola dágbére fáyé

Oríṣun àwòrán, OTHERS wákàtí 2 sẹ́yìn Iroyin to n tẹ wa lọwọlọwọ ni wipe ọkan lara…

Read More

Ilé ẹ̀kọ́ Chrisland School, àwọn òṣìṣẹ́, olùtajà tó wà níbi tí Whitney Adeniran ti kú yóò farahàn níwájú adájọ́

Oríṣun àwòrán, OTHERS wákàtí kan sẹ́yìn Ijọba ipinlẹ Eko ti fi ọrọ mii sita lori ẹsun…

Read More

Tani yóò lulẹ̀ nínú Adeleke àti Oyetola l’Ọ́ṣun? Òní ni iléẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn yóò dájọ̀

Oríṣun àwòrán, other wákàtí 2 sẹ́yìn Loni ọjọ Ẹti ni ile ẹjọ kotẹmilọrun yoo gbe idajọ…

Read More

Kí ìbò tó dé ni èmi àti Makinde ti ń sọ̀rọ̀, kò sí ìjà mọ́ láàrín wa – Olopoeyan

Oríṣun àwòrán, others wákàtí 3 sẹ́yìn Ọkan pataki ninu awọn aṣoju ẹgbẹ oṣelu ‘New Nigeria People’s…

Read More

Àwọn adigunjalè ṣèkọlù sí ilé adẹ́rìínpòṣónú, Woli Agba n’Ibadan

Oríṣun àwòrán, Woli Agba/Instagram ìṣẹ́jú 29 sẹ́yìn Adẹrinpoṣonu, Ayo Ajewole, ti ọpọ mọ si Woli Agbe…

Read More

Àṣírí tú bí ọlọ́pàá Amẹ́ríkà 7, òṣìṣẹ iléèwòsàn 3 ṣe fi tipátipá mú ọkùnrin yìí mọ́lẹ̀ títí tó fi kú

Contains upsetting scenes.Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ Contains upsetting scenes.…

Read More

Gbogbo nǹkan ló ní Àkókò – Davido wú ọ̀rọ̀ síta nípa ìṣẹ̀lẹ̀ aburú tó já lù ú

Oríṣun àwòrán, Davido/Instagram wákàtí 2 sẹ́yìn Olorin takasufee to tun jẹ ilumọọka ni Naijiria, David Adeleke,…

Read More

Oluwo sọ ọmọ tuntun rẹ̀ ní orúkọ ńlá kan, ẹ wà tú u wo, ẹ wo orùkọ́ aràmàǹdà!

Oríṣun àwòrán, OTHERS wákàtí kan sẹ́yìn Alayeluwa ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi ti ṣe…

Read More

Ẹ̀wọ̀n ọdún 241 ní wọ́n jù mí sí, lẹ́yìn tí mo lo ọdún 27, mo fojú rí fóònù, haà! Bí mo ṣe ṣe rèé – Bobby

Oríṣun àwòrán, BOBBY BOSTIC wákàtí 2 sẹ́yìn Ọkunrin ara orilẹede Amerika kan ti wọn fi sewọn…

Read More